ALPHABET OF PRAYER

A – Alaafia fun o.
B – Buburu kan ki yoo subu lu o.
D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori.
E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si
E – Ekun, ose ko ni je tire.
F – Funfun aye re ko ni dibaje.
G – Gunnugun ki ku l’ewe, wa dagba d’arugbo.
GB – Gbogbo idawole re a y’ori si rere.
H – Hausa, Yoruba, Ibo, gbogbo eya ati eniyan kaakiri agbaye ni yo koju si o se o loore.
I – Iwaju, iwaju l’opa ebiti re yo ma re si.
J – Jijade re, wiwole re, o ni
k’agbako.
K – Kukuru abi giga, osi ati ise ko ni je tire.
L – Loniloni wa r’aanu gba.
M- Monamona ati ara Olorun yoo tu awon ota re ka.
N – Naira, Euro, Dollar,
Pound, Yen, Yuan, gbogbo owo ati oro kaakiri agbaye pelu omo alalubarika ati alaafia yoo mu o l’ore, won o si fi ile re se ibugbe.
O – Ojurere ati aanu yoo ma to o leyin ni ojo aye re gbogbo.
O – Ojo ola re a dara.
P – Panpe aye o ni mu o
t’omotomo.
R – Rere ni agogo aye re o ma lu nigbagbogbo.
S – Suuru pelu itelorun ninu oro at’alaafia yoo ba o kale.
S – Sugbon ati abawon aye re ti poora loni.
T – Tomotomo, t’ebitebi, t’iletile o ni d’ero eyin.
U – U ki s’awati lede Ijesha; a o ni fi o s’awati laarin awon eniyan. Ulosiwaju (ilosiwaju), use rere (iserere), ati ubukun(ibunkun) yio je tire.
W – Wa ri ba ti se, wa r’ona gbe gba.
Y – Yara ibukun, ire, ati ayo ailopin loo ma ba e gbe titi ojo aye re……
AMIN (ASHE EDUMARE).
Iwo naa fi ranse si awon eeyan re ti o ba feran bi mo ti feran re

Posted from WordPress for Android

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s